LOGOSBASE
Bibles
About
Read yoruba Orin Dafidi 119 Bible Online
yoruba
Serafín de Ausejo, 1975
Biblia al Día
La Biblia del Oso 1569
Biblia del Oso 1573
La Biblia Hispanoamericana (Traducción Interconfesional, versión hispanoamericana), 2011
Biblia de Jerusalem 3-Edicion
Biblia de Jerusalén (1975)
Biblia Latinoamericana, 1995
La Palabra (BLPH), versión hispanoamericana, 2010
Biblia de nuestro Pueblo
La Biblia Textual
La Biblia Castilla 2003
SAGRADA BIBLIA
Biblia Corona de Jerusalen
Biblia Dios Habla Hoy, 1994
Dios Habla Hoy (DHH) versión española
Español Sagradas Escrituras (1569)
Sagrada Biblia — Universidad de Navarra, 2016
Jünemann Septuaginta en español
Traducción Kadosh Israelita Mesiánica
La Biblia de las Américas, 1997
El Libro del Pueblo de Dios
Biblia Septuaginta al Español (LXX)
La Santa Biblia, Nueva Biblia al Dia, 2008
Biblia de Jerusalén, 1998
Nueva Biblia de las Américas
Nueva Biblia Viva
Nueva Reina Valera
Nueva Traducción Viviente, 2009
La Santa Biblia, Nueva Versión Internacional, 2015
La Biblia: La Palabra de Dios para Todos, 2012
Reina Valera 2020
Biblia Platense
Reina Valera 2020
Reina-Valera 1995
Reina Valera Actualizada, 1989
Reina Valera Contemporánea, 2011
Reina Valera Gómez, 2010
Reina Valera Independiente, 2012
Español Reina Valera
Versión Biblia Libre
Versión Israelita Nazarena 2011
Amplified Bible, 2015
American Standard Version
Good News Bible
King James 1611
The Message
New International Version, 2011
luganda
dhopadhola
saamia
Alur
Ateso
lokele
kinyarwanda
Runyoro - rutooro
lunyore
kiswahili
kumam
lango
lugbara
anuak
lumasaaba
lunyole
ngakarimojong
bariba
fon
lango
maale
sango
sebat bet gurage
south west gbaya
kele
lega-mwenga
nande
ngando
songe
tetala
tshiluba
zande
basketo
koorete
majang
sekkacho
sekkacho
west central oromo
xamtanga
zemba
daasanach
digo
kuria
lubukusu
lulogooli
luo
pokomo
pokoot
rendile
suba
tharaka
tsotso
turkana
wanga
lambya
chopi
cisena
gitonga
ronga
tshwa
tsonga
zemba
abua
bali
bassa
berom
bura-pabir
ebira
efik
eggon
ejagham
eten
gungbe
hausa
hyam
icen
idege
idoma
igala
ikwere
irigwe
izere
kalabari
kirikeni
kutep
mada
mbula bwazza
mumuye
ninzo
north okpela arhe
nso
nya huba
obolo
tiv
tula
tyap
urhobo
yoruba
Hmong Njua
bahnar
Jarai
koho
Muong
Hmong Daw
Nung
Rade
Tày
Yupik
Gullah
Hopilàvayi
Hawaii Pidgin
Pennsylvania German
Ntcham
gen
Kabiyè
Moba
Akha
Hmong Njua
Iu Mien
Aramaic Peshita
Aukan
Caribbean Javanese
Patamona
Saamáka
Southern Sotho
Kahua
Ajië
Bilua
Sie
Futuna-Aniwa
Hindi, Fiji
Nguna Togoa Etafe North
Hano
West Ambae
East Ambae
Uripiv-Wala-Rano-Atchin
Varisi
Kuranko
Kono
West-Central Limba
romani
Binukid
Balangao
Central Bicolano
Caluyanon
Hiligaynon
Mansaka
Kapampangan
Pangasinan
Iloko
Amarakaeri
Arabela
Bora
Murui
Capanahua
Sharanahua
Matsés
Nomatsiguenga
Ticuna
Urarina
Nivaclé
Lengua Sur
Avañe'e
San Blas Kuna
Dulegaya
Western Panjabi
Zarma
Mískito
Mayangna
Ama
Auyana
Girawa
Bunama
Benabena
Kein
Baruya
Fore
Umanakaina
Guhu Samane
Golin
Halia
Huli
Iwam
Keapara
Kilivila
Kalam
Komba
Kurada
Kwanga
Keyagana
Kosena
Siane
Tungag
Managalasi
Orokaiva
Oksapmin
Folopa
Rotokas
Salt-Yui
Siane
Kanasi
Saposa
Seimat
Sembeleke
Weri
Usan
Yamano
Yau
Achang
Falam Chin
Lautu Chin
Mro-Khimi Chin
Hakha Chin
Khumi Chin
Siyin Chin
Tedim Chin
Zotung Chin
S'gaw Karen
Lashi
Matu Chin
Maru
Mün Chin
Tase Naga
Siyin Chin
Zou
Zokam
wa
Makhuwa-Shirima
Tarifit
Pohnpeian
Amuzgoan
Highland Puebla Nahuatl
Tabasco Chontal
Ojitlán Chinantec
Ozumacín de Chinantec
Latani Chinantec
Lalana Chinantec
Tlatepuzco Chinantec
El Nayar Cora
Chol
Tepetotutla Chinantec
Usila
Wixárika Niukiyari
Huastec
Ombeayiiüts
Jach-t’aan
San Jerónimo Tecóatl
Jalapa de Díaz
En Ngixo
Mixtec
Ocotepec Mixtec
Peñoles
Pinotepa Nacional Mixtec
Coatzospan
San Juan Colorado Mixtec
Silacayoapan Mixtec
Yosondúa Mixtec
Totontepec
Cristobál-Chayuco
Ixcatlán Mazatec
Mazatlán Mixe
Northern Oaxaca Nahuatl
Mezquital_Otomi
Querétaro Otomi
Highland Popoluca
Sayula Popoluca
Western Highland Purepecha
Biblia Mixe de Quetzaltepec
Upper Necaxa Totonac
Xasasti talacaxlan
Tojolabal
Xicotepec De Juárez Totonac
Papantla Totonac
Tlachichilco Tepehua
Tzeltal
Tzotzil
Bats'i k'op
Huarijio
Diuxi-tilantongo
Magdalena Peñasco
Yucateco
Ocotlán Zapotec
Isthmus Zapotec
Miahuatlán Zapotec
Ozolotepec Zapotec
Rincón Zapotec
Tabaa Zapotec
Mitla Zapotec
Coatecas Altas Zapotec
Copainalá Zoque
Choapan Zapotec
Yalálag Zapotec
Chichicapan Zapotec
Quioquitani-Quierí Zapotec
Medumba
Boros Dusun
Biatah Bidayuh
Kadazan Dusun
Iban
Western Penan
Timugon Murut
Wahau Kenyah
Lambya
Sena
Bribri
Bassa
Bandi
Grebo, Northern
Kpelle
Klao
Eastern Krahn
Western Krahn
Southern Kisi
Loma
Mano
Vai
Jamaican Patois
Alladian
Baoulé
Ebrié
Yocoboué Dida
Sénoufo, Cebaara
Sénoufo, Tagwana
Yaouré
Batak Angkola
Uab Meto
Casuarina Coast Asmat
Aralle-Tabulahan
Batak Toba
Besoa
Banggai
Bima
Biak
Berik
Balantak
Manggarai
Batak Dairi
Batak Simalungun
Batak Karo
Central Asmat
Upper Grand Valley Dani
Mid Grand Valley Dani
Western Dani
Galela
Ekari
Hatam
Sabu
Bambam
Abun
Da'a Kaili
Rampi
Lampung Api
Saluan
Malay, North Moluccan
Ma'anyan
Manikion
Mongondow
Mamasa
Una
Nduga
Ngaju
Nalca
Ninia Yali
Napu
Ot Danum
Uma
Central Malay
Rejang
Sahu
Sawi
Toraja-Sa'dan
Sangir
Ngalum
Tobelo
Talaud
Tamnim Citak
Tontemboan
Tombulu
Termanu
Citak
Damal
Wano
Silimo
Kambera
Malay, Manado
Pass Valley Yali
Angguruk Yali
Adi
Galo
Aimol
Anal
Apatani
Bagheli
Pahari, Mahasu
Haryanvi
Biete
Car_Nicobarese
Chambeali
Falam Chin
Hakha Chin
Dogri
Dhundari
Dimasa
Gaddi
Garhwali
Gangte
Goan Konkani
Hmar
Hrangkhol
Kodava
Kurumba, Kannada
Bilaspuri
Pahari, Kullu
Khiamniungan Naga
Komrem
Lamkang
Mandeali
Mannan
Karbi
Mising
Mewari
Muthuvan
Chang Naga
Konyak Naga
Rongmei Naga
Chothe Naga
Nocte Naga
Angami Naga
njo
Nyishi
Thangal Naga
Maram Naga
Tangkhul Naga
Monsang Naga
Moyon Naga
Northern Rengma Naga
Wancho Naga
Phom Naga
Pochuri Naga
Southern Rengma Naga
Chokri Naga
Sangtam Naga
Sumi Naga
Tase Naga
Zeme Naga
Paite
Paite Chin
Poumei Naga
Riang
Ranglong
Simte
Shekhawati
Tulu
Thado Chin
Tarao Naga
Kok Borok
Vaiphei
Adilabad Gondi
Kangri
Yimchungru Naga
Zou
Garifuna
Tolpan
Hadiyya
Kpelle
Kissi
Sosoxi
Dagbani
Southern Dagaare
Ga
Lelemi
Nzema
Sehwi
Konkomba
ewe
Twi Asante
Mandinka
Bohairic
Coptic
Sahidic Coptic
Chuj San Mateo
Kaqchikel
Kekchi
KekchíD
Q'anjob'al
Mam
Poqomchi'
Poqomchi
Q'anjob'al
A'ingae
Shuar
Chimborazo Highland Quichua
Imbabura Highland Quichua
Kichwa
Cañar Highland Quichua
Paikoka
Papiamento
Bribri
Beembe
Carapana
Comaltepec Chinantec
Cuiba
Jiwi
Namrrik
Guayabero
Camsá
Míkmawísimk
Macuna-Erulia
Noanamá
Piratapuyo
Saija
Wa’ikhana
Tunebo
Jukuna
Míkmawísimk
Awing
Aghem
Esimbi
Denya
Babanki
Mmen
Bakoko
Bum
Mokpwe
Akoose
Cuvok
Dii
Doyayo
ejagham
Ewondo
Fulfulde
Fulfulded
Gidar
South Giziga
Northwest Gbaya
Northwest Gbaya
Ngomba
kapsiki
Kenyang
Bafia
KapsikiDC
Karang
Nomaande
Limbum
Lamnso
Masana
North Mofu
Mpumpong
Mundani
Mousgoum
Samba Leko
Ngemba
Ngombale
Ngiemboon
Tigon Mbembe
Oku
Koonzime
Peere
Pinyin
Pana
Punu
Isu
Tupuri
Tunen
Vute
Weh
Nugunu
Yambeta
Yaouré
Birifor, Malba
Dagara, Northern
Gourmanchéma
Lyélé
Samo, Southern
Apalaí
Cubeo
Guaraní: Mbyá
Hixkaryána
Kadiwéu
Karaja
Sateré-Mawé
Nadëb
Paumarí
Terêna
Dahseyé
Kayapó
Xavánte
Nhengatu
Kalanga
Naro
Chipaya
Cavineña
Chiquitano
Ese Ejja
Simba
Guanano
Guarayu
Ignaciano
Wichí Lhamtés Nocten
Tacana
Belize Kriol
Bawm Chin
pap
Iyojwa'ja Chorote
Mocoví
Kabyle
Pilagá
Toba
Hiligaynon
Dari
Hazaragi
Shughni
Kuranko
Tunisian Arabic New Testament
Greek Orthodox New Testament
Moroccan Standard Translation
New_Van_Dyck_Arabic_Bible
New_Van_Dyck_Arabic_Bible
Arabic Bible: Easy-to-Read Version
live Arabic(targamet El hayah)
Original God's Name's Van Dyck Bible
Sharif Arabic Bible,
الكتاب المقدس، الترجمة العربية المبسطة
فانديك - Smith Van Dyke
True Meaning Arabic
KITAB SUCI
Библия Церковнославянская,
Новый Завет на церковнославянском языке
Библия Церковнославянская 1900
Библия Церковнославянская
Елизаветинская Библия, 1751
原文直譯參考用(CBOL)
Xitsonga
Contemporary Tsonga Bible 2024
Bibela ea Boitsépho 1890 (Sechuana Tlhaping - Moffatt Bible)
new_tumbuka_bible
Kutsal Kitap ve Deuterokanonik Kitaplar
Kutsal Kitap Yeni Ceviri, 2008
Kitab-ı Mukaddes Şirketi 2018
Te Tusi Tapu I Te Gana Tuvalu Lomiga Lua
Ыдыктыг Библия, 2011
Akuapem Twi Contemporary Bible 2020
Revised Akuapem Twi DC-KYERƐW KRONKRON
New Revised Asante Twi Bible
Ukrainian Contemporary Version 2023
Святе Письмо, Переклад Івана Хоменка, 1963
Біблія. Новий переклад УБТ Рафаїла Турконяка (1997-2007)
Біблія в пер. Івана Огієнка, 1962
Біблія, Куліш
Embimbiliya - Bíblia Sagrada em Umbundu
UGV Devanagari – किताब-ए मुक़द्दस
Roman Urdu Geo
اردو جیو ورژن
ھازىرقى زامان ئۇيغۇرچە تەرجىمىسىUyghurche Muqeddes Kitab Jemiyiti-
كتاب مقدّس, 1950
Vietnamese Bible: Easy-to-Read Version
Lời Chúa Cho Mọi Người, 2012
Kinh Thánh Bản Dịch Mới, New Vietnamese Bible, 2002
Revised Vietnamese Version Bible, 2010
Ўзбек тилидаги Муқаддас Китоб, 2013
Муқаддас Китоб Uzbek
Uzbek Muqaddas Kitob
Ўзбек тилидаги Муқаддас Китоб (ЎЗМК), 2013
O‘zbek tilidagi Muqaddas Kitob, 2013
Kinh Thánh Bản Dịch Mới
Vietnamese Bible (1934) – Kinh Thánh
Thánh Kinh: Bản Phổ thông
Kinh Thánh Tin Lành, 1934
Vietnamese Contemporary Bible (Kinh Thánh Hiện Đại)
Kivunjo New Testament 1999
Waray Samarenyo Meaning Based
Y Beibl Cymraeg Newydd, New Welsh Bible, 1988
Beibl Cymraeg Newydd Diwygiedig yn cynnwys yr Apocryffa 2004
Gobaith i Gymru
Cymdeithas y Beibl
William Morgan Bible 1588 original edition
YORUBA BIBLE CROWTHER VERSION – Bibeli Mimọ
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní, 2014
Bíbélì Mímọ́, Yoruba Bible, 2010
Contemporary Zulu Bible 2024
俄羅斯正教文理《希臘原文新約聖經》附《官話聖詠經》
淺文理和合本 - Easy Wenli Union Version,
神天聖書
Kernewek
Мукъаддес Китап къырымтатар тилинде,
Мукъаддес Китап
NOVI ZAVJET I PSALMI - 1. izd. -
Knjiga O Kristu
Biblija (Šarić)
Hrvatski Novi Zavjet
Biblija na hrvatskom
Krscanska sadasnjost
Biblija: suvremeni hrvatski prijevod
včetně DTK
překlad
Bible kralická
Bible Kralická
Bible kralická, 1579 (NZ)
Ekumenický překlad, 1979
Ekumenický překlad, 1977
Dr. Rudolf Col (NZ - 1947)
Český studijní překlad (2009)
Ceský studijní preklad
Dr. Jan Hejčl (1930)
Nová smlouva, 2000
Český studijní překlad Miloše Pavlíka
Bible v češtině se Strongovými čísly a morfologickými kódy
Překlad_NZ
Slovo na cestu 2000
Slovo na cestu 2012
Jan Ladislav Sýkora
Dansk Bibel
Bibelen på Hverdagsdansk
Danske Bibel 1871/1907
Det Danske Bibel
Lindberg Bibelen af 1866
Det Nye Testamente, Ole Wierøds
Dargi
EBV24_een_eigentijdse_Bijbelvertaling
een_eigentijdse_Bijbelvertaling edition Jongbloed 1995
LAYIDUKURA
Jula
dyu
La Sankta Biblio esparanto
La Sankta Biblio 1926 esparanto
La Sankta Biblio, sen Ĉapelo esparanto
Se Wsi Testamentti finnish
Se Wsi Testamentti 1548 sanasta sanaan
Coco Pyhä Raamattu, 1642
Coco Pyhä Raamattu 1642 apokryfit
Raamattu, 1776
Biblia 1776 apokryfit
Biblia. Kirkkoraamattu, 1938
Kirkkoraamattu 1933/38 alaviitteineen
Raamattu Kansalle, 2012
Pyhä Raamattu
Toivo Koilo Suuri Ilosanoma
Bible Bovet Bonnet
Bible de Genève
La Bible de Sacy
La Bible des Peuples, 1998
La Bible du Semeur, 2015
La Bible expliquée
La Bible en français courant, 1997
Bible de Pirot Clamer
Bible Vigouroux, 1902
La Bible de Zadoc Khan
La Bible Chouraqui
La Bible Augustin Crampon 1923
la Bible de Darby, 1890
French Darby,
French Darby 2013
La Bible en français courant
King James Française
Bible Segond
La Sainte Bible de Machaira 2016
La Bible Martin
Nouvelle Segond révisée, 1978
La Sainte Bible Ostervald
Bible Parole de Vie
Parole de Vie 2017
Bible Perret-Gentil et Rilliet, 1861
Sainte Bible Fillion, 1904
Ени Бааланты гагауз дилиндӓ, 2006
Eni Baalantı gagauz dilindä, 2006
Biblia SEPT
Nuevo Testamento na Mundurukú, 2010
Ge'ez NT – ሐዲስ ኪዳን በልሳነ ግእዝ
ახალი გადამუშავებული გამოცემა 2015
ადიშის ოთხთავი 897 წ. – ძველი მონუსკრიპტები
ქართული ბიბლია, სრული ვერსია
ქართული ბიბლია, სრული ვერსია
ბიბლია
მცხეთური ხელნაწერი–გ. მთაწმინდელი
საპატრიარქო
სბს–სტოკჰოლმი 2001
სბს–2013
ახალი ქართულით, Modern Georgian Bible, 1982
ძველი ქართულით
ახალი აღთქმა
ვანის ოთხთავი, Vani Gospels
Arndt Bibel deutsch
Alemannische Bibel NT
Abraham Meister NT
Albrecht Neues Testament und Psalmen, 1926
German Textbibel AT, 1906
Die Bibel in deutscher Fassung
Die Bengel Neuen Testament
De Wette
Die Heilige Schrift - Übersetzung des AT
Elberfelder Bibel 2006
Elberfelder 1871
Elberfelder 1905
Elberfelder Übersetzung
Die Bibel, Eß
Free Bible 2004 (DE)
Die Bibel. Übersetzung von Benjamin Fotteler, 2022
Neues Testament, Interlinearübersetzung
Kistemaker NT
Konkordantes Neues Testament , 1939
Textbibel von Kautzsch und Weizsäcker
Luther 1545 (Letzte Hand)
Luther Bibel, Wittenberg 1545, Letzte Hand mit Apokryphen
Luther Bibel 1912 mit Apokryphen
Menge-Bibel
Die Bibel – Übersetzt von Hermann Menge – Sonderausgabe
Münchener Neues Testament, 1998
NeÜ bibel.heute
Katholische Pattloch Bibel, 1980
Schlachter 1951
Die Piscator-Bibel NT
Die Schrift, 1929
Die Heilige Schrift, 1954
Stuttgarter Kepplerbibel, 1986
Studienübersetzung 2018
Tafelbibel, 1911
Darby Unrevidierte Elberfelder
Das Neue Testament. Grundtextnah übersetzt von W. Einert. 2018
Zürcher Bibel 2007
ZION-Bibel
Zürcher Bibel 2007
Zürcher Bibel 1931
Ghomala New Testament
Te B'aib'ara
KITABI HABARI MOPIOHE
H Αγία Γραφή στη Δημοτική (Filos Pergamos)
Νεοελληνική Μετάφραση Λόγου
Μετάφραση Νεόφυτου Βάμβα
Νέα Δημοτική Μετάφραση
Νέα Ελληνικά βιβλία, 1901
Μετάφραση Σπύρου Φίλου, Modern Greek Bible
Η Αγία Γραφή (Παλαιά και Καινή Διαθήκη)
Η Αγία Γραφή με τα Δευτεροκανονικά (Παλαιά και Καινή Διαθήκη)
The New Testament in Modern Greek (Vellas Version) – Η Καινή Διαθήκη του
Gujarati NT: Easy-To-Read Version, 2005
પવિત્ર બાઈબલ
Gujarati Bible – ગુજરાતી બાઇબલ
Gujarati Common Language Bible - પવિત્ર બાઇબલ C.L.
Gujarati Old Version
Delitzsch's Hebrew New Testament 1877, 1998 (with vowels)
Delitzsch's Hebrew New Testament 1877, 1998 (with vowels)
כֶּתֶר אֲרָם צוֹבָא - Tanah Aleppo Codex
Hebrew Study Bible, The text is the Westminster Leningrad Codex
Westminster Leningrad Codex (with vowels) hebrew
Modern Hebrew Bible, compilation from Westmister (OT) and Salkinson-Ginsburg (NT)
Westminster Leningrad Codex (morphological with vowels and accents)
Westminster Leningrad Codex (consonants)
Westminster Leningrad Codex (with vowels and accents)
תרגום יונתן בן עוזיאל - The Targum of Jonathan Ben Uzziel
Salkinson-Ginsburg Hebrew New Testament 1886, 2018 (with vowels)
Modern Hebrew New Testament 1976, 2010 (with vowels)
Hebrew Bible: Tanakh (Leningrad Codex)
Hindi Bible (WBTC)
Hindi Bible (BSI)
पवित्र बाइबल Hindi Holy Bible: Easy-to-Read Version
Hindi Holy Bible
Hindi Common Language Bible - पवित्र बाइबिल C.L.
Hindi O.V. (Re-edited), पवित्र बाइबिल
The Holy Bible in Hindi – पवित्र बाइबिल
Buka Helaga (Hiri Motu) 1993
Hungarian Bekes - Dalos NT, 1951
Budai Gergely Ujszovetseg forditasa
BIBLIA: Egyszerű fordítás
Újszövetség: élet, igazság és világosság, 2003
Hungarian Bible: Easy-to-Read Version, 2012
Magyar Bibliatársulat újfordítású Bibliája, 2014 (protestáns)
Szent István Társulati Biblia (katolikus)
Káldi-Neovulgáta (katolikus)
Kecskeméthy István Biblia fordítása, 1935
Magyar Újfordítású Biblia
Újszövetség egyszerű fordítás
Ibibio Contemporary Bible 2020
An Bíobla Naofa, 1981
Íslenska Biblían, Icelandic Bible
Icelandic DC Bible Biblían
icelandic Bible 1981 Biblían
Bibliya Yera 1951
Contemporary Kirundi Bible
Perjanjian Baru: Versi Mudah Dibaca, 2005
Alkitab dalam Bahasa Indonesia Masa Kini, 1985
Alkitab Terjemahan Lama
Alkitab Terjemahan Baru, 1974
Terjemahan Lama
Kitab Perjanjian Baru
An Bíobla Naofa 1981
Bibbia CEI 1971
Bibbia CEI 1974
Bibbia CEI 2008
Giovanni Diodati Bibbia, 1649
San Paolo, 1996
La Sacra Bibbia Versione Riveduta 2020 (R2)
La Nuova Diodati 1991
Nuova Riveduta 1994
Riveduta 1990
Riveduta Bibbia, 1927
Versione Diodati Riveduta
Traduzione Interconfessionale in Lingua Corrente 2014
文語訳/明治訳聖書(ルビあり), Classical Japanese - Bungo-yaku/Meiji-yaku, 1953
リビングバイブル, Japanese Contemporary Bible, 1978
ラゲ訳聖書(ルビあり), Raguet-yaku, 1910
口語訳聖書(ルビあり), Colloquial Japanese - Kougo-yaku, 1954/1955
新共同訳聖書, Japanese New Interconfessional Translation Bible - Shinkyodo-yaku, 1987
新改訳聖書 第三版, New Japanese Bible - Shinkai-yaku, 2003
現代訳聖書, Modern Japanese Bible, 1983
Kabardian New Testament, Genesis, Psalms – ХъыбарыфӀыр. ЩӀэдзапӀэр. Уэрэд ЛъапӀэхэр
Kitab Sutji, 1981
Jinghpaw Common Language Bible 2009
Jinghpaw Hanson Version Bible
Шин Бооцан, Эклц, Рут, Цецн Селвгүд, Псалмс, 2013
Swahilli
Swahilli
Swahilli
Swahilli
Swahilli
Swahilli
Swahilli
Swahilli
Swahilli
Swahilli
아가페 쉬운 성경, Agape Easy Bible, 1994
공동번역, Common Translation Bible, 1977
Korean Bible (American Standard Hangul)
Korean Easy Bible
현대인의 성경
Korean Modern Bible
새번역, Korean New Revised Standard Version
Korean Rentier Bible
개역한글
개역개정, New Revised Korean Version, 1998
새번역
현대어성경, Today's Korean Version, 1991
우리말사랑누리집, Korean Bible (Woorimal)
Мьзгини, 2011
Пәймана Ну (Инщил)
Kurmanji Încîl
Kurmanji Încîl, 2009
PEYMANA NÛ 2017 (ÎNCÎL)
Кыргыз тилиндеги Библия, 2004
Iyık Kitep (Ümüt Nuru 2004)
NT LS 2005 – Инжил ЛС (2005
Кыргыз тилиндеги Жаны Келишим (Луч Надежды)
Biblia Sacra juxta Vulgatam Clementinam
Clementine Vulgate
Nova_Vulgata
Nova_Vulgata DC
LATVIJAS BĪBELES BIEDRĪBA
1965. gada Bībeles izdevuma revidētais teksts
Latvian Gluck 8th edition - Glika Bībele
New Latvian Inter-confessional Bible with Deuterocanonicals
Lezgi New Testament – ЦӀийи Икьрар
Mokanda na Bomoi
Kosto Burbulio Biblijos vertimas (1999)
Biblija, arba Šventasis Raštas, 1999
Biblija arba Šventasis Raštas
K. Burbulio vertimas
Iš KJV Biblijos vertė D.Kundrotas
Lietuvos Biblijos draugija
Lietuvos Biblijos draugija DC
Biblija. Senasis Testamentas. Naujasis Testamentas, 2010
Plautdietsch (Low German) – De Bibel
De Bibel JHF
Tshiluba
Tshiluba
MUKANDA WANZAMBI
Свето Писмо (Гаврилова) 1990
Библија, Константинов
Библија, Константинов
Свето Писмо: Стандардна Библија 2006 (со девтероканонски книги)
Свето Писмо: Стандардна Библија 2006 (66 книги)
BIBILLYA Mareiyo Meele a Iruva
Mashami New Testament
Mofa New Testament
Makassar Version – KITTA' MATANGKASA
Ibibiliya mu Shimakonde Imbodi Yaambi na dimbande dya Imbodi Yakala
Makonde 2019
Malagasy
La Bible en Malgache
DIEM PROTESTANTA
Dikateny Iombonana Eto Madagasikara
Malayalam
Maltese Bible with DC – IL-BIBBJA IL-KOTBA MQADDSA
Bible Maori, 1858
Maori Bible 1952 – Te Paipera Tapu
Ngünechen ñi Küme Dungu Mapudungun
Mapudungun
MAASAI REVISED PROTESTANT
Maasai Bible – Biblia Sinyati
Ngowili Yekpei Numu Kpɛlɛɛ Va
KIMERU BIBLE PROTESTANT EDITION
Fɨso Fi
Baibul, Mizo
Mizo Lushai
Mizo_Old_version
Ариун Библи, Mongolian Ariun Bible, 2004
Ariun Bible 2013 – Ариун Библи 2013
SEBR SÕNGO, 1998
Morisien
Moore -WẼNNAAM SEBRE
Oria Indian ଓଡିଆ ବାଇବେଲ
ପବିତ୍ର ବାଇବଲ
Khoekhoegowab
Navajo
Oshindonga-Ombiimbeli Ondjapuki
Oshindonga-Ombiimbeli Ondjapuki 2008
Nepali-पवित्र बाइबल
Nepali New Revised Version, 2012
Soera Ni’amoni’ö, 2009
Nogai
Ndebele-IBhayibhili Elingcwele 2006
Bibelen – Guds Ord 2017
Bibelen - Guds Ord Hverdagsbibelen
Det Norske Bibelselskap, 1930
Norwegian 1978
Bibelen 2011 bokmål
Norsk Bibel 88
Nyamwezi
Buku Lopatulik
Buku Loyera - Chichewa
Chichewa Buku Lopatulika Bible 2014
Tonga
nynorsk 2011
nynorsk 1978
nynorsk 1938
Studentmållagsbibelen, 1921
Oriya Bible: Easy-to-Read Version
Odia Old Version
Хуыцауы Дзырд иронау
Библи: Сыгъдӕг
Pampanga-Ing Mayap a Balita Biblia
Pangasinan
Pashto (Nangahari) — د پښتو مقدس کتاب
Pashto Bible (Yusufzai) — د پښتو مقدس کتاب
Persian Farsi
Persian New Millenium Version
Old Persian Version, 1895, ترجمه قدیم
Persian Old Version, 2011
Today's Farsi مژده برای عصر جدید
Today's Persian Version Revised مژده برای عصر جدید - ویرایش
De Bibel JHF Plautdietsch Low German
Plautdietsch Low German
Sun
Biblia Brzeska, 1563
Biblia Gdańska, 1881
Biblia Tysiąclecia IV
Biblia Tysiąclecia IV, 2003
Biblia Tysiąclecia II, 1971
Biblia Tysiąclecia V, 1999
Biblia Ekumeniczna, 2018
Nowa Biblia Gdańska, 2012
Biblia Paulistów, 2016
Biblia Poznańska I, 1975
Biblia to jest Pismo Święte Starego i Nowego Przymierza I, 2018
Uwspółcześniona Biblia Gdańska, 2018
Biblia Warszawska, 1975
Ewangeliczny Instytut Biblijny
Biblia Almeida Século 21
Almeida Revista e Atualizada, 1959
Almeida Corrigida Fiel, 2007
Bíblia Almeida Recebida, 2011
Almeida Revisada de Acordo
Bíblia Ave-Maria, 1959
Bíblia de Estudo Pentecostal, 2009
a BÍBLIA para todos Edição Comum, 2009
Corrigida Fiel, 1753-1995
Bíblia CNBB (Nova Capa), 2002
Difusora Bíblica Franciscanos Capuchinhos
Bíblia King James Atualizada, 2001
Bíblia King James 1611
Bíblia Livre - Nestle 1904
Bíblia Livre - Textus Receptus
Bíblia Literal do Texto Tradicional, 2015
Bíblia A Mensagem
Nova Bíblia Viva, 2007
Nova Versão Internacional
Biblia Viva 2002
Bíblia Sagrada, Nova Versão Transformadora, 2016
Bíblia Sagrada, Nova Versão Transformadora
Tradução O Livro em Português Comum
Portuguese Corrigida Fiel (1753/1995)
Portuguese Version
Tradução Brasileira, 2010
Portuguese Holy Bible: Easy-to-Read Translation
Punjabi Holy Bible: Easy-to-Read Version-ਪਵਿੱਤਰ ਬਾਈਬਲ
Indian Revised Version (IRV) Punjabi - 2019 – ਇੰਡਿਅਨ ਰਿਵਾਇਜ਼ਡ ਵਰਜ਼ਨ (IRV)
Punjabi Old Version Bible (BSI) – ਪਵਿੱਤਰ ਬਾਈਬਲ O.V.
Tayta Diosninchi Isquirbichishan
DIOSPA QHELQACHISQ Quechua
Quechua Bolivia DC Bible
CHUYA QELLQA La Biblia en Quechua de Ayacucho 2012
Biblia Revisión Chuya Qellqa 1992 – Chuya Qellqa 1992
Quechua Cuzco Bible 1988
Diospa Simin Qelqa
Cook Islands Maori Bible – Bibilia Tapu
Biblia_Dumitru_Cornilescu_2024_romania
Biblia în versuri
Biblia de la Blaj, 1795
Biblia Regele Carol II, 1939
Biblia Traducerea Fidela, 2015
Biblia în Versiune Actualizată, 2018
Ediția Dumitru Cornilescu revizuită 2022
Versiunea Bartolomeu Anania, 2001
Versiunea Biblică Trinitariană, 2002
Versiunea_Dumitru_Cornilescu_1924
Romanian Cornilescu Reference Bible Cyrillic script – Библия Думитру Корнилеску
Baltic Romani Bible 2019 – Библия - Пэ Балтитко Романи чиб (Романэс) 2019
Biblija - Pe Baltitko Romani čib (Romanes) 2019 Baltic Romani Bible
O Debleskro Drom - I Bibla an o Romano Rakepen 2021
Kalderash Romani Cornilescu Bible 2020 (Romania)
Библия-Агапэ, 2004
Библия под ред. М.П. Кулакова и М.М. Кулакова, 2015
Священное Писание, Восточный перевод, 2009
Восточный перевод, 2013
Священное Писание, Восточный перевод, версия «Аллах» 2009
Восточный перевод, версия с «Аллахом», 2013
Священное Писание, Восточный перевод, таджикская версия, 2009
Восточный перевод, версия для Таджикистана, 2013
Библия Юбилейная
Еврейские Писания (Ветхий Завет) Макарий, 1867
Святая Библия: Современный перевод
Святая Библия: Современный перевод, 2014
Танах Сборник лучших переводов (5 авторов)
Библия в русском переводе с приложениями ("Брюссельская Библия"), 1973
MMA SHIYYA
Samburu
Samoan Old Version Bible – O LE TUSI PAIA
La Bible en Sango courant – Mbeti ti Nzapa
Sanskrit
Santali
KITAB SUCI ZABUR INJIL
Scots Gaelic 1992 – Am Bìoball Gàidhlig 199
Cibverano Cipsa Cisena
Cibverano Cipsa
Библија: Савремени српски превод
New Serbian Translation - Cyrillic Нови српски превод, 2017
Novi srpski prevod, 2017
Библија, Караджич, 1865
štampan latinicom serbian Biblija
NQAARIIT NE ROOG
САҤА КЭС ТЫЛ
Библия- Yakut
Библия- Yakut 2021
Kishambala
Bhaibheri Dzvene MuChiShona Chanhasi
Bhaibhiri Idzva rechiShona
Original Shona Union Bible 1949 Baiberi Magwaro Matȿene aMŋari
Shona Union Version 2002
Sidama_Qullaawa _Maxaafa
Slovenský Ekumenický Biblia, 2008
Botekov preklad
当代译本修订版 - Chinese Contemporary Bible, 2012
中文英王钦定本 - Chinese King James Version
当代圣经 - Chinese Living Bible Simplified, Red letter edition, 1979
新英语译本 - Chinese New English Translation, 2011
新译本 - Chinese New Version, 1992
圣经恢复本串珠 - Recovery Version Cross References, 2003
新标点和合本 - Chinese Union New Punctuation, 1988
吕振中译本 - Lü Zheng Zhong, 1970
京委本圣经 - Peking Committee Bible, 1899
Sheng Jing - Pinyin (Romanized Chinese)
和合本修订版 - Revised Chinese Union Version, 2010
现代中文译本 - Today's Chinese Version, 1997
思高圣经 - Studium Biblicum Version Simplified, 1968
原文直译参考用(CBOL)
Sindhi Common Language New Testament
Sinhala New Revised Version 2018
Sinhala Revised Old Version
Slovenský evanjelický preklad.
Preklad Jozefa Roháčka AV
Svätá Biblia v preklade Jozefa Roháčka, 1936
Sväté Písmo – katolícky preklad
Biblia – Evanjelický preklad
Dalmatin Bible 1584
Sveto Pismo, Slovenian Bible, 2008
Somali Bible, 2008
BORANA BIBLE – KITAABA WAAQA
BORANA BIBLE – KITAABA WAAQA
KITAABKA QUDUUSKA AH
Јаҥы Кереес
Јаҥы Кереес, Алтай тили
Ndebele
Sukuma Bible 2015 – Bibilia Ilagano Lya Kale 2015
Svenska Karl XII:s Bibel, 1873
nuBibeln (Swedish Contemporary Bible)
Svenska Bibelsällskapet
Svenska Folkbibeln, 1998
Svenska 1917
Den Heliga Skrift
Ang Biblia, 1978
Ang Biblia, 2001
Ang Bagong Ang Biblia
Ang Salita ng Dios, 2015
Magandang Balita Biblia, 2005
Tagalog Form-Based Bible
Magandang Balita Biblia
TAITA BIBLE – Biblia Ilagho Jiboie Kwa Wandu Wose
Китоби Муқаддас 1992, 2016
Tamil Romanised Bible 2019
திருவிவிலியம் - Thiruviviliam
இந்திய சமகால தமிழ் மொழிபெயர்ப்பு 2022 - Indian Tamil Contemporary Version 2022
பரிசுத்த பைபிள் - Tamil Easy-to-Read Version
இந்திய திருத்திய பதிப்பு 2017, Tamil Indian Revised Version 2017 - TIRV
பரிசுத்த வேதாகமம் 2017 - Tamil Holy Bible 2017 - Old Version - O.V
இந்திய திருத்திய பதிப்பு 2019, Tamil Indian Revised Version 2019 - TIRV
Изге Язма, 2015
పరిశుద్ధ గ్రంథము, Telugu Bible: Easy-to-Read Version
పవిత్ర బైబిల్
Ebaibuli 1961
Holy Bible: Easy-to-Read Translation – พระคริสตธรรมคัมภีร์: ฉบับอ่านเข้าใจง่าย
New Thai Version (NTV) – พระคัมภีร์ ฉบับแปลใหม่
ไทยฉบับ KJV, Thai KJV, 2003
Thai New Contemporary Version (ฉบับอมตธรรมร่วมสมัย)
Thai Holy Bible – พระคริสตธรรมคัมภีร์ Thai OV 83
ฉบับมาตรฐาน, 2011
Thai Holy Bible 1971 – พระคัมภีร์ไทย ฉบับ 1971
Central Tibetan Bible
Tibetan — པོད་སྐད་Tibetan Old Testament 2011
དམ་པའི་གསུང་རབ་བོད་འགྱུར་གསར་མ།-New Tibetan Bible
መ/ቅዱስ ትግርኛ, Tigrigna Bible, 1997
መ/ቅዱስ ትግርኛ, Tigrigna Bible, 1
Ȧŋlemrȧnɛ Ȧfu
TIV OLD BIBLE NO REF – ICIGHAN BIBILO
KO E TOH TAPU KATOA TONGA
Pa-khek-lé Pe̍h-ōe-jī Sèng-keng, 1933 - Barclay Taiwanese Bible, 1933 - Full Romanization
巴克禮台語聖經漢羅 1933 - Barclay Taiwanese Bible, 1933 - Mixed Sino-Romanization
當代譯本修訂版 - Chinese Contemporary Bible, 2012
中文英王欽定本 - Chinese King James Version
當代聖經 - Chinese Living Bible, Red letter edition, 1979
新英語譯本 - Chinese New English Translation, 2011
新譯本 - Chinese New Version, 1992
聖經恢復本串珠 - Recovery Version Cross References, 2003
新標點和合本串珠 - Chinese Union New Punctuation Cross References, 1988
呂振中譯本 - Lü Zheng Zhong, 1970
京委本聖經 - Peking Committee Bible, 1899
現代中文譯本 - Today's Chinese Version, 1997
環球聖經譯本 - Worldwide Chinese Bible
北京官話譯本, 1878
Orin Dafidi 119 - yoruba bible
Orin Dafidi
Jẹnẹsisi
Ẹkisodu
Lefitiku
Nọmba
Diutaronomi
Joṣua
Àwọn Adájọ́
Ìwé ti Rutu
ÌWÉ KINNI TI SAMUẸLI
ÌWÉ KEJI TI SAMUẸLI
Ìwé Kinni ti Àwọn Ọba
Ìwé Keji ti Àwọn Ọba
Ìwé Kinni ti Kronika
Ìwé Keji ti Kronika
Ìwé ti Ẹsra
Ìwé ti Nehemaya
Ìwé ti Ẹsita
Ìwé ti Jobu
Orin Dafidi
Ìwé Òwe
Ìwé Oníwàásù
Orin Solomoni
Ìwé ti Aisaya
Ìwé ti Jeremaya
Ìwé Ẹkún Jeremaya
Ìwé ti Isikiẹli
Ìwé ti Daniẹli
Ìwé ti Hosia
Ìwé ti Joẹli
Ìwé ti Amosi
Ìwé ti Obadaya
Ìwé ti Jona
Ìwé ti Mika
Ìwé ti Nahumu
Ìwé ti Habakuku
Ìwé ti Sefanaya
Ìwé ti Hagai
Ìwé ti Sakaraya
Ìwé ti Malaki
Ìyìnrere Jesu Kristi lati Ọwọ́ Matiu
Ìyìnrere Jesu Kristi lati Ọwọ́ Maku
Ìyìnrere Jesu Kristi lati Ọwọ́ Luku
Ìyìnrere Jesu Kristi lati Ọwọ́ Johanu
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI
Ìwé Paulu sí Àwọn Ará Romu
Ìwé Kinni Paulu sí Àwọn Ará Kọrinti
Ìwé Keji Paulu sí Àwọn Ará Kọrinti
Ìwé Paulu sí Àwọn Ará Galatia
Ìwé Paulu sí Àwọn Ará Efesu
Ìwé Paulu sí Àwọn Ará Filipi
Ìwé Paulu sí Àwọn Ará Kolose
Ìwé Kinni Paulu sí Àwọn Ará Tẹsalonika
Ìwé Keji Paulu sí Àwọn Ará Tẹsalonika
Ìwé Kinni Paulu sí Timoti
Ìwé Keji Paulu sí Timoti
Ìwé Paulu sí Titu
Ìwé Paulu sí Filemoni
Ìwé sí Àwọn Heberu
Ìwé lati Ọ̀dọ̀ Jakọbu
Ìwé Kinni lati Ọ̀dọ̀ Peteru
Ìwé Keji lati Ọ̀dọ̀ Peteru
Ìwé Kinni ti Johanu
Ìwé Keji ti Johanu
Ìwé Kẹta ti Johanu
Ìwé lati Ọ̀dọ̀ Juda
Ìwé Ifihan
119
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
39
40
41
42
43
44
45
46
47
48
49
50
51
52
53
54
55
56
57
58
59
60
61
62
63
64
65
66
67
68
69
70
71
72
73
74
75
76
77
78
79
80
81
82
83
84
85
86
87
88
89
90
91
92
93
94
95
96
97
98
99
100
101
102
103
104
105
106
107
108
109
110
111
112
113
114
115
116
117
118
119
120
121
122
123
124
125
126
127
128
129
130
131
132
133
134
135
136
137
138
139
140
141
142
143
144
145
146
147
148
149
150
Orin Dafidi 119
1
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ìgbé ayé wọn kò lábàwọ́n, àní àwọn tí ń rìn gẹ́gẹ́ bí òfin OLUWA.
2
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ń pa òfin rẹ̀ mọ́, tí wọn ń fi tọkàntọkàn ṣe ìfẹ́ rẹ̀.
3
Àwọn tí wọn kò dẹ́ṣẹ̀, ṣugbọn tí wọn ń rìn ní ọ̀nà rẹ̀.
4
O ti pàṣẹ pé kí á fi tọkàntọkàn pa òfin rẹ mọ́,
5
Ìbá ti dára tó tí mo bá lè dúró ṣinṣin ninu ìlànà rẹ!
6
Òun ni ojú kò fi ní tì mí, nítorí pé òfin rẹ ni mò ń tẹ̀lé.
7
N óo yìn ọ́ pẹlu inú mímọ́, bí mo ṣe ń kọ́ ìlànà òdodo rẹ.
8
N óo máa pa òfin rẹ mọ́, má kọ̀ mí sílẹ̀ patapata.
9
Báwo ni ọdọmọkunrin ṣe lè mú kí ọ̀nà rẹ̀ mọ́? Nípa títẹ̀lé ọ̀rọ̀ rẹ ni.
10
Tọkàntọkàn ni mo fi ń ṣe ìfẹ́ rẹ, má jẹ́ kí n ṣìnà kúrò ninu òfin rẹ.
11
Mo ti fi ọ̀rọ̀ rẹ sọ́kàn, kí n má baà ṣẹ̀ ọ́.
12
Ìyìn ni fún ọ, OLUWA, kọ́ mi ní ìlànà rẹ!
13
Mo fi ẹnu mi kéde gbogbo àṣẹ tí o pa.
14
Mo láyọ̀ ninu pípa òfin rẹ mọ́, bí ẹni tí ó ní ọpọlọpọ ọrọ̀.
15
N óo máa ṣe àṣàrò ninu òfin rẹ, n óo sì kọjú sí ọ̀nà rẹ.
16
N óo láyọ̀ ninu àwọn ìlànà rẹ, n kò ní gbàgbé ọ̀rọ̀ rẹ.
17
Ṣe ọpọlọpọ oore fún èmi iranṣẹ rẹ, kí n lè wà láàyè, kí n sì máa tẹ̀lé ọ̀rọ̀ rẹ.
18
Là mí lójú, kí n lè rí àwọn nǹkan ìyanu tí ó wà ninu òfin rẹ.
19
Àlejò ni mí láyé, má fi òfin rẹ pamọ́ fún mi.
20
Òùngbẹ títẹ̀lé òfin rẹ ń gbẹ ọkàn mi, nígbà gbogbo.
21
O bá àwọn onigbeeraga wí, àwọn ẹni ègún, tí wọn kò pa òfin rẹ mọ́.
22
Mú ẹ̀gàn ati àbùkù wọn kúrò lára mi, nítorí pé mo ti pa òfin rẹ mọ́.
23
Bí àwọn ìjòyè tilẹ̀ gbìmọ̀ràn ọ̀tẹ̀ nítorí mi, sibẹ, èmi iranṣẹ rẹ yóo ṣe àṣàrò lórí ìlànà rẹ.
24
Àwọn òfin rẹ ni dídùn inú mi, àwọn ni olùdámọ̀ràn mi.
25
Mo di ẹni ilẹ̀, sọ mí di alààyè gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ rẹ.
26
Nígbà tí mo jẹ́wọ́ gbogbo ìṣe mi, o dá mi lóhùn; kọ́ mi ní ìlànà rẹ.
27
La òfin rẹ yé mi, n óo sì máa ṣe àṣàrò lórí iṣẹ́ ìyanu rẹ.
28
Ìrẹ̀wẹ̀sì bá ọkàn mi nítorí ìbànújẹ́, mú mi lọ́kàn le gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ rẹ.
29
Mú ìwà èké jìnnà sí mi, kí o sì fi oore ọ̀fẹ́ kọ́ mi ní òfin rẹ.
30
Mo ti yan ọ̀nà òtítọ́, mo ti fi ọkàn sí òfin rẹ.
31
Mo pa òfin rẹ mọ́, OLUWA, má jẹ́ kí ojú ó tì mí.
32
N óo yára láti pa òfin rẹ mọ́, nígbà tí o bá mú òye mi jinlẹ̀ sí i.
33
OLUWA, kọ́ mi ní ìlànà rẹ, n óo sì pa wọ́n mọ́ dé òpin.
34
Là mí lóye, kí n lè máa pa òfin rẹ mọ́, kí n sì máa fi tọkàntọkàn pa wọ́n mọ́.
35
Tọ́ mi sí ọ̀nà nípa òfin rẹ, nítorí pé mo láyọ̀ ninu rẹ̀.
36
Mú kí ọkàn mi fà sí òfin rẹ, kí ó má fà sí ọrọ̀ ayé.
37
Yí ojú mi kúrò ninu wíwo nǹkan asán, sọ mí di alààyè ní ọ̀nà rẹ.
38
Mú ìlérí rẹ ṣẹ fún iranṣẹ rẹ, àní, ìlérí tí o ṣe fún àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ.
39
Mú ẹ̀gàn tí ń bà mí lẹ́rù kúrò, nítorí pé ìlànà rẹ dára.
40
Wò ó, ọkàn mi fà sí ati máa tẹ̀lé ìlànà rẹ, sọ mí di alààyè nítorí òdodo rẹ!
41
Fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ hàn mí, OLÚWA, kí o sì gbà mí là gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ.
42
Nígbà náà ni n óo lè dá àwọn tí ń gàn mí lóhùn, nítorí mo gbẹ́kẹ̀lé ọ̀rọ̀ rẹ.
43
Má gba ọ̀rọ̀ òtítọ́ rẹ lẹ́nu mi rárá, nítorí ìrètí mi ń bẹ ninu ìlànà rẹ.
44
N óo máa pa òfin rẹ mọ́ nígbà gbogbo, lae ati laelae.
45
N óo máa rìn fàlàlà, nítorí pé mo tẹ̀lé ìlànà rẹ.
46
N óo máa sọ̀rọ̀ òfin rẹ níwájú àwọn ọba, ojú kò sì ní tì mí.
47
Mo láyọ̀ ninu òfin rẹ, nítorí tí mo fẹ́ràn rẹ̀.
48
Mo bọ̀wọ̀ fún àṣẹ rẹ tí mo fẹ́ràn, n óo sì máa ṣe àṣàrò lórí ìlànà rẹ.
49
Ranti ọ̀rọ̀ tí o bá èmi iranṣẹ rẹ sọ, èyí tí ó fún mi ní ìrètí.
50
Ohun tí ó ń tù mí ninu ní àkókò ìpọ́njú ni pé: ìlérí rẹ mú mi wà láàyè.
51
Àwọn onigbeeraga ń kẹ́gàn mi gidigidi, ṣugbọn n ò kọ òfin rẹ sílẹ̀.
52
Mo ranti òfin rẹ àtijọ́, OLUWA, ọkàn mi sì balẹ̀.
53
Inú mi á máa ru, nígbà tí mo bá rí àwọn eniyan burúkú, tí wọn ń rú òfin rẹ.
54
Òfin rẹ ni mò ń fi ń ṣe orin kọ, lákòókò ìrìn àjò mi láyé.
55
Mo ranti orúkọ rẹ lóru; OLUWA, mo sì pa òfin rẹ mọ́:
56
Èyí ni ìṣe mi: Èmi a máa pa òfin rẹ mọ́.
57
OLUWA, ìwọ nìkan ni mo ní; mo ṣe ìlérí láti pa òfin rẹ mọ́.
58
Tọkàntọkàn ni mò ń wá ojurere rẹ, ṣe mí lóore gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ.
59
Nígbà tí mo ronú nípa ìṣe mi, mo yipada sí ìlànà rẹ;
60
mo yára, bẹ́ẹ̀ ni n kò lọ́ra láti pa òfin rẹ mọ́.
61
Bí okùn àwọn eniyan burúkú tilẹ̀ wé mọ́ mi, n kò ní gbàgbé òfin rẹ.
62
Mo dìde lọ́gànjọ́ láti yìn ọ́, nítorí ìlànà òdodo rẹ.
63
Ọ̀rẹ́ gbogbo àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ ni mí, àní, àwọn tí wọn ń pa òfin rẹ mọ́.
64
OLUWA, ayé kún fún ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀; kọ́ mi ní ìlànà rẹ.
65
OLUWA, o ti ṣeun fún èmi iranṣẹ rẹ, gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ.
66
Fún mi ní òye ati ìmọ̀ pípé, nítorí mo ní igbagbọ ninu àṣẹ rẹ.
67
Kí o tó jẹ mí níyà, mo yapa kúrò ninu òfin rẹ; ṣugbọn nisinsinyii, mò ń mú àṣẹ rẹ ṣẹ.
68
OLUWA rere ni ọ́, rere ni o sì ń ṣe; kọ́ mi ní ìlànà rẹ.
69
Àwọn onigbeeraga ti wé irọ́ mọ́ mi lẹ́sẹ̀, ṣugbọn èmi fi tọkàntọkàn pa òfin rẹ mọ́.
70
Ọkàn wọn ti yigbì, ṣugbọn èmi láyọ̀ ninu òfin rẹ.
71
Ìpọ́njú tí mo rí ṣe mí ní anfaani, ó mú kí n kọ́ nípa ìlànà rẹ.
72
Òfin rẹ níye lórí fún mi, ó ju ẹgbẹẹgbẹrun wúrà ati fadaka lọ.
73
Ìwọ ni o mọ mí, ìwọ ni o dá mi, fún mi ní òye kí n lè kọ́ òfin rẹ.
74
Inú àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ yóo máa dùn nígbà tí wọ́n bá rí mi, nítorí pé mo ní ìrètí ninu ọ̀rọ̀ rẹ.
75
OLUWA, mo mọ̀ pé ìdájọ́ rẹ tọ̀nà, ati pé lórí ẹ̀tọ́ ni o pọ́n mi lójú.
76
Jẹ́ kí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ máa tù mí ninu, gẹ́gẹ́ bí ìlérí tí o ṣe fún èmi, iranṣẹ rẹ.
77
Ṣàánú mi, kí n lè wà láàyè, nítorí pé òfin rẹ ni ìdùnnú mi.
78
Jẹ́ kí ojú ó ti àwọn onigbeeraga, nítorí wọ́n ṣe àrékérekè sí mi láìnídìí; ní tèmi, n óo máa ṣe àṣàrò lórí òfin rẹ.
79
Jẹ́ kí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ tọ̀ mí wá, kí wọ́n lè mọ òfin rẹ.
80
Níti pípa òfin rẹ mọ́, jẹ́ kí n pé, kí ojú má baà tì mí.
81
Mo wá ìgbàlà rẹ títí, àárẹ̀ mú ọkàn mi; ṣugbọn mo ní ìrètí ninu ọ̀rọ̀ rẹ.
82
Mo fojú sọ́nà títí, agara dá mi, níbi tí mo tí ń retí ìmúṣẹ ìlérí rẹ. Mo ní, “Nígbà wo ni o óo tù mí ninu?”
83
Mo dàbí agbè ọtí tí ó ti di àlòpatì, sibẹ, n kò gbàgbé ìlànà rẹ.
84
Èmi iranṣẹ rẹ yóo ti dúró pẹ́ tó? Nígbà wo ni ìwọ óo dájọ́ fún àwọn tí ń ṣe inúnibíni mi?
85
Àwọn onigbeeraga ti gbẹ́ kòtò sílẹ̀ dè mí, àní, àwọn tí kì í pa òfin rẹ mọ́.
86
Gbogbo òfin rẹ ló dájú; ràn mí lọ́wọ́, nítorí wọ́n ń fi ìwà èké ṣe inúnibíni mi.
87
Wọ́n fẹ́rẹ̀ pa mí run láyé, ṣugbọn n kò kọ ìlànà rẹ sílẹ̀.
88
Dá ẹ̀mí mi sí gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, kí n lè máa mú gbogbo àṣẹ rẹ ṣẹ.
89
OLUWA, títí lae ni ọ̀rọ̀ rẹ fìdí múlẹ̀ lọ́run.
90
Òtítọ́ rẹ wà láti ìrandíran; o ti fi ìdí ayé múlẹ̀, ó sì dúró.
91
Ohun gbogbo wà gẹ́gẹ́ bí ìlànà rẹ, títí di òní, nítorí pé iranṣẹ rẹ ni gbogbo wọn.
92
Bí kò bá jẹ́ pé òfin rẹ jẹ́ ìdùnnú mi, ǹ bá ti ṣègbé ninu ìpọ́njú.
93
Lae, n kò ní gbàgbé ẹ̀kọ́ rẹ, nítorí pé, nípasẹ̀ wọn ni o fi mú mi wà láyé.
94
Ìwọ ni o ni mí, gbà mí; nítorí pé mo ti kọ́ ẹ̀kọ́ rẹ.
95
Àwọn eniyan burúkú ba dè mí, wọ́n fẹ́ pa mí run, ṣugbọn mò ń ṣe àṣàrò lórí òfin rẹ.
96
Mo ti rí i pé kò sí ohun tí ó lè pé tán, àfi òfin rẹ nìkan ni kò lópin.
97
Mo fẹ́ràn òfin rẹ lọpọlọpọ! Òun ni mo fi ń ṣe àṣàrò tọ̀sán-tòru.
98
Ìlànà rẹ mú mi gbọ́n ju àwọn ọ̀tá mi lọ, nítorí pé òun ni ó ń darí mi nígbà gbogbo.
99
Òye mi ju ti àwọn olùkọ́ mi lọ, nítorí pé ìlànà rẹ ni mo fi ń ṣe àṣàrò.
100
Òye mi ju ti àwọn àgbà lọ, nítorí pé mo gba ẹ̀kọ́ rẹ.
101
N kò rin ọ̀nà ibi kankan, kí n lè pa òfin rẹ mọ́.
102
N kò yapa kúrò ninu òfin rẹ, nítorí pé o ti kọ́ mi.
103
Ọ̀rọ̀ rẹ dùn mọ́ mi pupọ, ó dùn ju oyin lọ.
104
Nípa ẹ̀kọ́ rẹ ni mo fi ní òye, nítorí náà mo kórìíra gbogbo ìwà èké.
105
Ọ̀rọ̀ rẹ ni àtùpà fún ẹsẹ̀ mi, òun ni ìmọ́lẹ̀ sí ọ̀nà mi.
106
Mo ti búra, n óo sì mú un ṣẹ, pé n óo máa pa òfin òdodo rẹ mọ́.
107
Ojú ń pọ́n mi lọpọlọpọ, sọ mí di alààyè, OLUWA, gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ.
108
Gba ẹbọ ìyìn àtọkànwá mi, OLUWA, kí o sì kọ́ mi ní ìlànà rẹ.
109
Ayé mi wà ninu ewu nígbà gbogbo, ṣugbọn n kò gbàgbé òfin rẹ.
110
Àwọn eniyan burúkú ti dẹ okùn sílẹ̀ dè mí, ṣugbọn n kò kọ ìlànà rẹ sílẹ̀.
111
Ìlànà rẹ ni ogún mi títí lae, nítorí pé òun ni ayọ̀ mi.
112
Mo ti pinnu láti máa tẹ̀lé ìlànà rẹ nígbà gbogbo, àní, títí dé òpin.
113
Mo kórìíra àwọn oníyèméjì, ṣugbọn mo fẹ́ràn òfin rẹ.
114
Ìwọ ni ibi ìpamọ́ mi ati asà mi, mo ní ìrètí ninu ọ̀rọ̀ rẹ.
115
Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi, ẹ̀yin aṣebi, kí n lè pa òfin Ọlọrun mi mọ́.
116
Gbé mi ró gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ, kí n lè wà láàyè, má sì dójú ìrètí mi tì mí.
117
Gbé mi ró, kí n lè wà láìléwu, kí n lè máa ka ìlànà rẹ sí nígbà gbogbo.
118
O ti kọ gbogbo àwọn tí ó yapa kúrò ninu ìlànà rẹ sílẹ̀, nítorí pé asán ni gbogbo ẹ̀tàn wọn.
119
O ti pa àwọn eniyan burúkú tì, bí ìdàrọ́ irin, nítorí náà ni mo ṣe fẹ́ràn ìlànà rẹ.
120
Mo wárìrì nítorí pé mo bẹ̀rù rẹ, mo sì bẹ̀rù ìdájọ́ rẹ.
121
Mo ti ṣe ohun tí ó tọ́ tí ó sì yẹ, má fi mí sílẹ̀ fún àwọn tí wọn ń ni mí lára.
122
Ṣe ìlérí ìrànlọ́wọ́ fún ire èmi iranṣẹ rẹ, má sì jẹ́ kí àwọn onigbeeraga ni mí lára.
123
Mo fojú sọ́nà títí, agara dá mi, níbi tí mo tí ń retí ìgbàlà rẹ, ati ìmúṣẹ ìlérí òdodo rẹ.
124
Ṣe sí èmi iranṣẹ rẹ, gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, kí o sì kọ́ mi ní ìlànà rẹ.
125
Iranṣẹ rẹ ni mí, fún mi lóye, kí n lè mọ ìlànà rẹ.
126
OLUWA, ó tó àkókò fún ọ láti ṣe nǹkankan, nítorí àwọn eniyan ń rú òfin rẹ.
127
Nítorí náà ni èmi ṣe fẹ́ràn òfin rẹ ju wúrà lọ; àní, ju ojúlówó wúrà.
128
Nítorí náà, èmi ń tẹ̀lé gbogbo ẹ̀kọ́ rẹ, mo sì kórìíra gbogbo ọ̀nà èké.
129
Òfin rẹ dára, nítorí náà ni mo ṣe ń pa wọ́n mọ́.
130
Ìṣípayá ọ̀rọ̀ rẹ a máa fúnni ní ìmọ́lẹ̀, a sì máa fi òye fún àwọn onírẹ̀lẹ̀.
131
Mo la ẹnu, mò ń mí hẹlẹ, nítorí pé mò ń lépa òfin rẹ.
132
Kọjú sí mi kí o ṣe mí lóore bí o ti máa ń ṣe sí àwọn tí ó fẹ́ràn rẹ.
133
Mú ẹsẹ̀ mi dúró gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ, má sì jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ kankan jọba lórí mi.
134
Gbà mí lọ́wọ́ ìnilára àwọn eniyan, kí n lè máa tẹ̀lé ìlànà rẹ.
135
Jẹ́ kí ojú rẹ mọ́lẹ̀ sí ara èmi iranṣẹ rẹ; kí o sì kọ́ mi ní ìlànà rẹ.
136
Omijé ń dà lójú mi pòròpòrò, nítorí pé àwọn eniyan kò pa òfin rẹ mọ́.
137
Olódodo ni ọ́, OLUWA, ìdájọ́ rẹ sì tọ́.
138
Òdodo ni o fi pa àṣẹ rẹ, òtítọ́ patapata ni.
139
Mò ń tara gidigidi, nítorí pé àwọn ọ̀tá mi gbàgbé ọ̀rọ̀ rẹ.
140
A ti yẹ ọ̀rọ̀ rẹ wò fínnífínní, ó dúró ṣinṣin, mo sì fẹ́ràn rẹ̀.
141
Bí mo tilẹ̀ kéré, tí ayé sì kẹ́gàn mi, sibẹ n kò gbàgbé ìlànà rẹ.
142
Òdodo rẹ wà títí lae, òtítọ́ sì ni òfin rẹ.
143
Ìyọnu ati ìpayà dé bá mi, ṣugbọn mo láyọ̀ ninu òfin rẹ.
144
Òdodo ni ìlànà rẹ títí lae, fún mi ní òye kí n lè wà láàyè.
145
Tọkàntọkàn ni mo fi ń ké pè ọ́, OLUWA, dá mi lóhùn; n óo sì máa tẹ̀lé ìlànà rẹ.
146
Mo ké pè ọ́; gbà mí, n óo sì máa mú àṣẹ rẹ ṣẹ.
147
Mo jí ní òwúrọ̀ kutukutu, mo sì kígbe fún ìrànlọ́wọ́; mò ń retí ìmúṣẹ ọ̀rọ̀ rẹ.
148
N kò fi ojú ba oorun ní gbogbo òru, kí n lè máa ṣe àṣàrò lórí ọ̀rọ̀ rẹ.
149
Gbóhùn mi nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, OLÚWA, dá mi sí nítorí òtítọ́ rẹ.
150
Àwọn tí ń ṣe inúnibíni mi súnmọ́ tòsí; wọ́n jìnnà sí òfin rẹ.
151
Ṣugbọn ìwọ wà nítòsí, OLUWA, òtítọ́ sì ni gbogbo òfin rẹ.
152
Ó pẹ́ tí mo ti kọ́ ninu ìlànà rẹ, pé o ti fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ títí lae.
153
Wo ìpọ́njú mi, kí o gbà mí, nítorí n kò gbàgbé òfin rẹ.
154
Gba ẹjọ́ mi rò, kí o sì gbà mí, sọ mí di alààyè gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ.
155
Ìgbàlà jìnnà sí àwọn eniyan burúkú, nítorí wọn kò wá ìlànà rẹ.
156
Àánú rẹ pọ̀, OLUWA, sọ mí di alààyè gẹ́gẹ́ bí òtítọ́ rẹ.
157
Àwọn tí ń ṣe inúnibíni mi ati àwọn ọ̀tá mi pọ̀, ṣugbọn n kò yapa kúrò ninu ìlànà rẹ.
158
Mò ń wo àwọn ọ̀dàlẹ̀ pẹlu ìríra, nítorí wọn kì í pa òfin rẹ mọ́.
159
Wo bí mo ti fẹ́ ẹ̀kọ́ rẹ tó! Dá mi sí gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.
160
Òtítọ́ ni gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ, gbogbo òfin òdodo rẹ ni yóo máa wà títí lae.
161
Àwọn ìjòyè ń ṣe inúnibíni mi láìnídìí, ṣugbọn mo bẹ̀rù ọ̀rọ̀ rẹ tọkàntọkàn.
162
Mo láyọ̀ ninu ọ̀rọ̀ rẹ, bí ẹni pé mo ní ọpọlọpọ ìkógun.
163
Mo kórìíra èké ṣíṣe, ara mi kọ̀ ọ́, ṣugbọn mo fẹ́ràn òfin rẹ.
164
Nígbà meje lojoojumọ ni mò ń yìn ọ́ nítorí òfin òdodo rẹ.
165
Alaafia ńláńlá ń bẹ fún àwọn tí ó fẹ́ràn òfin rẹ, kò sí ohun tí ó lè mú wọn kọsẹ̀.
166
Mò ń retí ìgbàlà rẹ, OLUWA, mo sì ń pa àwọn òfin rẹ mọ́.
167
Mò ń pa àṣẹ rẹ mọ́, mo fẹ́ràn wọn gidigidi.
168
Mo gba ẹ̀kọ́ rẹ, mo sì ń tẹ̀lé ìlànà rẹ; gbogbo ìṣe mi ni ò ń rí.
169
Jẹ́ kí igbe mi dé ọ̀dọ̀ rẹ, OLUWA, fún mi ní òye gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ.
170
Jẹ́ kí ẹ̀bẹ̀ mi dé iwájú rẹ, kí o sì gbà mí là gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ.
171
Ẹnu mi yóo kún fún ìyìn rẹ, pé o ti kọ́ mi ní ìlànà rẹ.
172
N óo máa fi ọ̀rọ̀ rẹ ṣe orin kọ, nítorí pé gbogbo òfin rẹ ni ó tọ̀nà.
173
Múra láti ràn mí lọ́wọ́, nítorí pé mo ti gba ẹ̀kọ́ rẹ.
174
Ọkàn mi ń fà sí ìgbàlà rẹ, OLUWA; òfin rẹ sì ni inú dídùn mi.
175
Dá mi sí kí n lè máa yìn ọ́, sì jẹ́ kí òfin rẹ ràn mí lọ́wọ́.
176
Mo ti ṣìnà bí aguntan tó sọnù; wá èmi, iranṣẹ rẹ, rí, nítorí pé n kò gbàgbé òfin rẹ.